Àìsáyà 61:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ní tiyín, a ó máa pè yín ní àlùfáà Jèhófà;+Wọ́n á máa pè yín ní òjíṣẹ́ Ọlọ́run wa. Ẹ máa jẹ ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,+Ẹ sì máa fi ògo* wọn yangàn.
6 Ní tiyín, a ó máa pè yín ní àlùfáà Jèhófà;+Wọ́n á máa pè yín ní òjíṣẹ́ Ọlọ́run wa. Ẹ máa jẹ ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,+Ẹ sì máa fi ògo* wọn yangàn.