Àìsáyà 52:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 Jí! Jí! Gbé agbára wọ̀,+ ìwọ Síónì!+ Wọ aṣọ rẹ tó rẹwà,+ ìwọ Jerúsálẹ́mù, ìlú mímọ́! Torí ẹni tí kò dádọ̀dọ́* àti aláìmọ́ kò ní wọ inú rẹ mọ́.+ Ìfihàn 21:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bákan náà mo rí ìlú mímọ́ náà, Jerúsálẹ́mù Tuntun, ó ń ti ọ̀run sọ̀ kalẹ̀ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run,+ bí ìyàwó tí a ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ fún ọkọ rẹ̀.+
52 Jí! Jí! Gbé agbára wọ̀,+ ìwọ Síónì!+ Wọ aṣọ rẹ tó rẹwà,+ ìwọ Jerúsálẹ́mù, ìlú mímọ́! Torí ẹni tí kò dádọ̀dọ́* àti aláìmọ́ kò ní wọ inú rẹ mọ́.+
2 Bákan náà mo rí ìlú mímọ́ náà, Jerúsálẹ́mù Tuntun, ó ń ti ọ̀run sọ̀ kalẹ̀ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run,+ bí ìyàwó tí a ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ fún ọkọ rẹ̀.+