-
2 Àwọn Ọba 15:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Ní ọdún kejìléláàádọ́ta Asaráyà ọba Júdà, Pékà+ ọmọ Remaláyà di ọba lórí Ísírẹ́lì ní Samáríà, ogún (20) ọdún ló sì fi ṣàkóso.
-