Àìsáyà 49:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àmọ́ Síónì ń sọ ṣáá pé: “Jèhófà ti pa mí tì,+ Jèhófà sì ti gbàgbé mi.”+ Àìsáyà 54:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí Jèhófà pè ọ́ bí ìyàwó tí wọ́n pa tì, tí ẹ̀dùn ọkàn sì bá,*+Bí ìyàwó tí wọ́n fẹ́ nígbà ọ̀dọ́, tí wọ́n wá kọ̀ sílẹ̀,” ni Ọlọ́run rẹ wí.
6 Torí Jèhófà pè ọ́ bí ìyàwó tí wọ́n pa tì, tí ẹ̀dùn ọkàn sì bá,*+Bí ìyàwó tí wọ́n fẹ́ nígbà ọ̀dọ́, tí wọ́n wá kọ̀ sílẹ̀,” ni Ọlọ́run rẹ wí.