Émọ́sì 1:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí náà, màá rán iná sí Témánì,+Á sì jó àwọn ilé gogoro tó láàbò ti Bósírà run.’+