Ẹ́kísódù 14:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Áńgẹ́lì Ọlọ́run tòótọ́+ tó ń lọ níwájú àwùjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò níwájú, ó sì bọ́ sí ẹ̀yìn wọn, ọwọ̀n ìkùukùu* tó wà níwájú wọn wá bọ́ sí ẹ̀yìn wọn, ó sì dúró síbẹ̀.+ Ẹ́kísódù 23:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín+ kó lè dáàbò bò yín lójú ọ̀nà, kó sì mú yín wá síbi tí mo ti ṣètò sílẹ̀.+
19 Áńgẹ́lì Ọlọ́run tòótọ́+ tó ń lọ níwájú àwùjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò níwájú, ó sì bọ́ sí ẹ̀yìn wọn, ọwọ̀n ìkùukùu* tó wà níwájú wọn wá bọ́ sí ẹ̀yìn wọn, ó sì dúró síbẹ̀.+
20 “Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín+ kó lè dáàbò bò yín lójú ọ̀nà, kó sì mú yín wá síbi tí mo ti ṣètò sílẹ̀.+