Jeremáyà 21:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Èmi fúnra mi máa na apá mi àti ọwọ́ mi tó lágbára jáde láti bá yín jà+ pẹ̀lú ìbínú àti ìrunú àti ìkannú ńlá.+
5 Èmi fúnra mi máa na apá mi àti ọwọ́ mi tó lágbára jáde láti bá yín jà+ pẹ̀lú ìbínú àti ìrunú àti ìkannú ńlá.+