-
Àìsáyà 8:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Lẹ́yìn náà, mo bá wòlíì obìnrin náà* ní àṣepọ̀,* ó sì lóyún, ó wá bí ọmọkùnrin kan.+ Jèhófà wá sọ fún mi pé: “Sọ ọmọ náà ni Maheri-ṣalali-háṣí-básì, 4 torí kí ọmọ náà tó mọ bí wọ́n ṣe ń pe, ‘Bàbá mi!’ àti ‘Ìyá mi!’ wọ́n máa kó àwọn ohun àmúṣọrọ̀ Damásíkù àti ẹrù ogun Samáríà lọ níwájú ọba Ásíríà.”+
-