Àìsáyà 33:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ilẹ̀ náà ń ṣọ̀fọ̀,* kò sì lọ́ràá mọ́. Ojú ti Lẹ́bánónì;+ ó ti jẹrà. Ṣárónì ti dà bí aṣálẹ̀,Báṣánì àti Kámẹ́lì sì gbọn ewé wọn dà nù.+
9 Ilẹ̀ náà ń ṣọ̀fọ̀,* kò sì lọ́ràá mọ́. Ojú ti Lẹ́bánónì;+ ó ti jẹrà. Ṣárónì ti dà bí aṣálẹ̀,Báṣánì àti Kámẹ́lì sì gbọn ewé wọn dà nù.+