Àìsáyà 51:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà.+ Wọ́n máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì,+Ayọ̀ tí kò lópin sì máa dé wọn ládé.*+ Ìdùnnú àti ayọ̀ máa jẹ́ tiwọn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ sì máa fò lọ.+
11 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà.+ Wọ́n máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì,+Ayọ̀ tí kò lópin sì máa dé wọn ládé.*+ Ìdùnnú àti ayọ̀ máa jẹ́ tiwọn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ sì máa fò lọ.+