Àìsáyà 5:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àwọn tó ń fi okùn ẹ̀tàn fa ẹ̀bi wọn lọ gbé,Tí wọ́n sì ń fi okùn kẹ̀kẹ́ ẹṣin fa ẹ̀ṣẹ̀ wọn;19 Àwọn tó ń sọ pé: “Kó jẹ́ kí iṣẹ́ Rẹ̀ yára kánkán;Kó tètè dé, ká lè rí i. Kí ohun tí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì ní lọ́kàn* ṣẹ,Ká lè mọ̀ ọ́n!”+ Àìsáyà 29:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà sọ pé: “Àwọn èèyàn yìí ń fi ẹnu wọn sún mọ́ mi,Wọ́n sì ń fi ètè wọn bọlá fún mi,+Àmọ́ ọkàn wọn jìnnà gan-an sí mi;Àṣẹ èèyàn tí wọ́n kọ́ wọn ló sì ń mú kí wọ́n máa bẹ̀rù mi.+
18 Àwọn tó ń fi okùn ẹ̀tàn fa ẹ̀bi wọn lọ gbé,Tí wọ́n sì ń fi okùn kẹ̀kẹ́ ẹṣin fa ẹ̀ṣẹ̀ wọn;19 Àwọn tó ń sọ pé: “Kó jẹ́ kí iṣẹ́ Rẹ̀ yára kánkán;Kó tètè dé, ká lè rí i. Kí ohun tí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì ní lọ́kàn* ṣẹ,Ká lè mọ̀ ọ́n!”+
13 Jèhófà sọ pé: “Àwọn èèyàn yìí ń fi ẹnu wọn sún mọ́ mi,Wọ́n sì ń fi ètè wọn bọlá fún mi,+Àmọ́ ọkàn wọn jìnnà gan-an sí mi;Àṣẹ èèyàn tí wọ́n kọ́ wọn ló sì ń mú kí wọ́n máa bẹ̀rù mi.+