Àìsáyà 54:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 54 “Kígbe ayọ̀, ìwọ àgàn tí kò bímọ!+ Tújú ká, kí o sì kígbe ayọ̀,+ ìwọ tí o kò ní ìrora ìbímọ rí,+Torí àwọn ọmọ* ẹni tó ti di ahoro pọ̀Ju àwọn ọmọ obìnrin tó ní ọkọ,”*+ ni Jèhófà wí.
54 “Kígbe ayọ̀, ìwọ àgàn tí kò bímọ!+ Tújú ká, kí o sì kígbe ayọ̀,+ ìwọ tí o kò ní ìrora ìbímọ rí,+Torí àwọn ọmọ* ẹni tó ti di ahoro pọ̀Ju àwọn ọmọ obìnrin tó ní ọkọ,”*+ ni Jèhófà wí.