Jẹ́nẹ́sísì 10:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn ọmọ Hámù ni Kúṣì, Mísíráímù,+ Pútì+ àti Kénáánì.+ Jẹ́nẹ́sísì 10:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mísíráímù bí Lúdímù,+ Ánámímù, Léhábímù, Náfítúhímù,+