-
2 Kíróníkà 27:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) ni Jótámù+ nígbà tó jọba, ọdún mẹ́rìndínlógún (16) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jérúṣà ọmọ Sádókù.+ 2 Ó ń ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Jèhófà bí Ùsáyà bàbá rẹ̀ ti ṣe,+ àmọ́ ní tirẹ̀, kò wọ ibi tí kò yẹ kó wọ̀ nínú tẹ́ńpìlì Jèhófà.+ Síbẹ̀, àwọn èèyàn náà ṣì ń hùwà ibi.
-