18 Àwọn Filísínì+ náà tún wá kó ẹrù àwọn èèyàn ní àwọn ìlú Ṣẹ́fẹ́là+ àti Négébù ti Júdà, wọ́n sì gba Bẹti-ṣémẹ́ṣì,+ Áíjálónì,+ Gédérótì, Sókò àti àwọn àrọko rẹ̀, Tímúnà+ àti àwọn àrọko rẹ̀ pẹ̀lú Gímúsò àti àwọn àrọko rẹ̀; wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé níbẹ̀.