-
2 Kíróníkà 32:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tiẹ̀ sọ ohun tó jù bẹ́ẹ̀ lọ sí Jèhófà Ọlọ́run tòótọ́ àti sí Hẹsikáyà ìránṣẹ́ rẹ̀.
-
-
2 Kíróníkà 32:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Wọ́n sọ̀rọ̀ sí Ọlọ́run Jerúsálẹ́mù bí wọ́n ṣe sọ̀rọ̀ sí àwọn ọlọ́run ará ayé, tí wọ́n jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ èèyàn.
-