Àìsáyà 28:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ní báyìí, ẹ má fini ṣe yẹ̀yẹ́,+Ká má bàa tún mú kí àwọn ìdè yín le sí i,Torí mo ti gbọ́ látọ̀dọ̀ Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogunPé a ti pinnu láti pa gbogbo ilẹ̀ náà* run.+
22 Ní báyìí, ẹ má fini ṣe yẹ̀yẹ́,+Ká má bàa tún mú kí àwọn ìdè yín le sí i,Torí mo ti gbọ́ látọ̀dọ̀ Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogunPé a ti pinnu láti pa gbogbo ilẹ̀ náà* run.+