2 Àwọn Ọba 18:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ní ọdún kẹrìnlá Ọba Hẹsikáyà, Senakérúbù ọba Ásíríà+ wá gbéjà ko gbogbo ìlú olódi Júdà, ó sì gbà wọ́n.+ Àìsáyà 10:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Àháà! ará Ásíríà,+Ọ̀pá tí mo fi ń fi ìbínú mi hàn+Àti ọ̀pá ọwọ́ wọn tí mo fi ń báni wí!
13 Ní ọdún kẹrìnlá Ọba Hẹsikáyà, Senakérúbù ọba Ásíríà+ wá gbéjà ko gbogbo ìlú olódi Júdà, ó sì gbà wọ́n.+