Àwọn Onídàájọ́ 20:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó yá, ẹ fi àwọn ọkùnrin Gíbíà+ tí kò ní láárí yẹn lé wa lọ́wọ́, ká lè pa wọ́n, ká sì mú ohun tí kò dáa kúrò ní Ísírẹ́lì.”+ Àmọ́ àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì kò fetí sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó jẹ́ arákùnrin wọn.
13 Ó yá, ẹ fi àwọn ọkùnrin Gíbíà+ tí kò ní láárí yẹn lé wa lọ́wọ́, ká lè pa wọ́n, ká sì mú ohun tí kò dáa kúrò ní Ísírẹ́lì.”+ Àmọ́ àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì kò fetí sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó jẹ́ arákùnrin wọn.