Òwe 15:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Jèhófà jìnnà réré sí àwọn ẹni burúkú,Àmọ́ ó máa ń gbọ́ àdúrà àwọn olódodo.+