Dáníẹ́lì 5:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ara ọba wá funfun,* èrò ọkàn rẹ̀ sì kó jìnnìjìnnì bá a, ìgbáròkó rẹ̀ mì,+ àwọn orúnkún rẹ̀ sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbá ara wọn.
6 Ara ọba wá funfun,* èrò ọkàn rẹ̀ sì kó jìnnìjìnnì bá a, ìgbáròkó rẹ̀ mì,+ àwọn orúnkún rẹ̀ sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbá ara wọn.