-
Ìfihàn 18:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 A ò sì ní gbọ́ ìró àwọn akọrin tí wọ́n ń ta háàpù sí orin tí wọ́n ń kọ nínú rẹ mọ́ àti ìró àwọn olórin, àwọn tó ń fun fèrè àti àwọn tó ń fun kàkàkí. A ò sì ní rí oníṣẹ́ ọnà kankan tó ń ṣe iṣẹ́ èyíkéyìí nínú rẹ mọ́ láé, bẹ́ẹ̀ la ò ní gbọ́ ìró ọlọ kankan nínú rẹ mọ́ láé.
-