Jeremáyà 48:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Sọ̀ kalẹ̀ kúrò nínú ògo rẹ,Sì jókòó nínú òùngbẹ,* ìwọ ọmọbìnrin tó ń gbé ní Díbónì,+Nítorí ẹni tó pa Móábù run ti wá gbéjà kò ọ́,Ó sì máa pa àwọn ibi olódi rẹ run.+
18 Sọ̀ kalẹ̀ kúrò nínú ògo rẹ,Sì jókòó nínú òùngbẹ,* ìwọ ọmọbìnrin tó ń gbé ní Díbónì,+Nítorí ẹni tó pa Móábù run ti wá gbéjà kò ọ́,Ó sì máa pa àwọn ibi olódi rẹ run.+