Diutarónómì 14:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Ọmọ Jèhófà Ọlọ́run yín lẹ jẹ́. Ẹ ò gbọ́dọ̀ kọ ara yín ní abẹ+ tàbí kí ẹ fá iwájú orí yín* torí òkú.+
14 “Ọmọ Jèhófà Ọlọ́run yín lẹ jẹ́. Ẹ ò gbọ́dọ̀ kọ ara yín ní abẹ+ tàbí kí ẹ fá iwájú orí yín* torí òkú.+