Émọ́sì 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘“Nítorí ìdìtẹ̀* mẹ́ta Móábù+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí pé ó jó egungun ọba Édómù láti fi ṣe ẹfun.
2 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘“Nítorí ìdìtẹ̀* mẹ́ta Móábù+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí pé ó jó egungun ọba Édómù láti fi ṣe ẹfun.