ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 31:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Gbàrà tí wọ́n parí gbogbo èyí, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó wà níbẹ̀ jáde lọ sí àwọn ìlú Júdà, wọ́n fọ́ àwọn ọwọ̀n òrìṣà sí wẹ́wẹ́,+ wọ́n gé àwọn òpó òrìṣà lulẹ̀,*+ wọ́n sì wó àwọn ibi gíga+ àti àwọn pẹpẹ+ lulẹ̀ ní gbogbo Júdà àti Bẹ́ńjámínì pẹ̀lú Éfúrémù àti Mánásè+ títí wọ́n fi pa wọ́n run pátápátá, lẹ́yìn náà, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pa dà sí àwọn ìlú wọn, kálukú pa dà sídìí ohun ìní rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́