Diutarónómì 28:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 O máa fẹ́ obìnrin sọ́nà, àmọ́ ọkùnrin míì á fipá bá a lò pọ̀. O máa kọ́ ilé, àmọ́ o ò ní gbé ibẹ̀.+ O máa gbin àjàrà, àmọ́ o ò ní rí i lò.+ Hósíà 8:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí afẹ́fẹ́ ni wọ́n ń gbìn,Ìjì sì ni wọ́n máa ká.+ Kò sí pòròpórò kankan tó ní ọkà tí ó gbó;*+Ohunkóhun tó bá hù kò ní so èso tó wúlò fún ìyẹ̀fun. Bí èyíkéyìí bá sì so, àwọn àjèjì* yóò gbé e mì.+
30 O máa fẹ́ obìnrin sọ́nà, àmọ́ ọkùnrin míì á fipá bá a lò pọ̀. O máa kọ́ ilé, àmọ́ o ò ní gbé ibẹ̀.+ O máa gbin àjàrà, àmọ́ o ò ní rí i lò.+
7 Nítorí afẹ́fẹ́ ni wọ́n ń gbìn,Ìjì sì ni wọ́n máa ká.+ Kò sí pòròpórò kankan tó ní ọkà tí ó gbó;*+Ohunkóhun tó bá hù kò ní so èso tó wúlò fún ìyẹ̀fun. Bí èyíkéyìí bá sì so, àwọn àjèjì* yóò gbé e mì.+