Ìsíkíẹ́lì 29:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí náà, màá bá ìwọ àti odò Náílì rẹ jà, màá mú kí ilẹ̀ Íjíbítì dá páropáro kó sì gbẹ, yóò di ahoro,+ láti Mígídólì+ dé Síénè,+ títí dé ààlà Etiópíà.
10 Torí náà, màá bá ìwọ àti odò Náílì rẹ jà, màá mú kí ilẹ̀ Íjíbítì dá páropáro kó sì gbẹ, yóò di ahoro,+ láti Mígídólì+ dé Síénè,+ títí dé ààlà Etiópíà.