Sáàmù 78:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ó ṣe àwọn ohun àgbàyanu níwájú àwọn baba ńlá wọn,+Ní ilẹ̀ Íjíbítì, ní agbègbè Sóánì.+ Ìsíkíẹ́lì 30:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Màá pa Pátírọ́sì+ run, màá dá iná sí Sóánì, màá sì dá Nóò* lẹ́jọ́.+