Émọ́sì 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Màá pa àwọn tó ń gbé Áṣídódì run,+Àti àwọn tó ń ṣàkóso* ní Áṣíkẹ́lónì;+Màá fìyà jẹ Ẹ́kírónì,+Àwọn Filísínì tó ṣẹ́ kù yóò sì ṣègbé,”+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.’
8 Màá pa àwọn tó ń gbé Áṣídódì run,+Àti àwọn tó ń ṣàkóso* ní Áṣíkẹ́lónì;+Màá fìyà jẹ Ẹ́kírónì,+Àwọn Filísínì tó ṣẹ́ kù yóò sì ṣègbé,”+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.’