Míkà 7:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹni tó dáa jù nínú wọn dà bí ẹ̀gún,Ẹni tó jẹ́ olóòótọ́ jù láàárín wọn burú ju ọgbà ẹlẹ́gùn-ún lọ. Ọjọ́ tí àwọn olùṣọ́ rẹ sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ àti ọjọ́ ìyà rẹ yóò dé.+ Ẹ̀rù yóò sì bà wọ́n.+
4 Ẹni tó dáa jù nínú wọn dà bí ẹ̀gún,Ẹni tó jẹ́ olóòótọ́ jù láàárín wọn burú ju ọgbà ẹlẹ́gùn-ún lọ. Ọjọ́ tí àwọn olùṣọ́ rẹ sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ àti ọjọ́ ìyà rẹ yóò dé.+ Ẹ̀rù yóò sì bà wọ́n.+