-
1 Àwọn Ọba 7:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ọdún mẹ́tàlá (13) ló gba Sólómọ́nì láti kọ́ ilé* rẹ̀,+ títí ó fi parí ilé náà látòkèdélẹ̀.+
2 Ó kọ́ Ilé Igbó Lẹ́bánónì,+ gígùn ilé náà jẹ́ ọgọ́rùn-ún (100) ìgbọ̀nwọ́,* fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ àádọ́ta (50) ìgbọ̀nwọ́, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ọgbọ̀n (30) ìgbọ̀nwọ́, ó kọ́ ọ sórí ọ̀wọ́ mẹ́rin òpó igi kédárì;+ àwọn ìtì igi kédárì sì wà lórí àwọn òpó náà.
-