Ìsíkíẹ́lì 26:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Yóò di ibi tí wọ́n ń sá àwọ̀n sí láàárín òkun.’+ “‘Torí èmi fúnra mi ti sọ̀rọ̀,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí, ‘àwọn orílẹ̀-èdè yóò sì kó o ní ẹrù. Ìsíkíẹ́lì 26:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ fún Tírè nìyí: ‘Tí ìró ìṣubú rẹ bá dún, tí àwọn tó ń kú lọ* ń kérora, tí wọ́n pa ọ̀pọ̀ láàárín rẹ, ǹjẹ́ àwọn erékùṣù ò ní mì jìgìjìgì?+
5 Yóò di ibi tí wọ́n ń sá àwọ̀n sí láàárín òkun.’+ “‘Torí èmi fúnra mi ti sọ̀rọ̀,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí, ‘àwọn orílẹ̀-èdè yóò sì kó o ní ẹrù.
15 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ fún Tírè nìyí: ‘Tí ìró ìṣubú rẹ bá dún, tí àwọn tó ń kú lọ* ń kérora, tí wọ́n pa ọ̀pọ̀ láàárín rẹ, ǹjẹ́ àwọn erékùṣù ò ní mì jìgìjìgì?+