Ìsíkíẹ́lì 26:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Yóò fi idà pa àwọn agbègbè tó wà ní ìgbèríko rẹ run, yóò mọ odi láti gbéjà kò ọ́, yóò mọ òkìtì láti dó tì ọ́, yóò sì fi apata ńlá bá ọ jà. 9 Yóò fi igi* tí wọ́n fi ń fọ́ ògiri kọ lu ògiri rẹ, yóò sì fi àáké* wó àwọn ilé gogoro rẹ.
8 Yóò fi idà pa àwọn agbègbè tó wà ní ìgbèríko rẹ run, yóò mọ odi láti gbéjà kò ọ́, yóò mọ òkìtì láti dó tì ọ́, yóò sì fi apata ńlá bá ọ jà. 9 Yóò fi igi* tí wọ́n fi ń fọ́ ògiri kọ lu ògiri rẹ, yóò sì fi àáké* wó àwọn ilé gogoro rẹ.