ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 5:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ó yá, ẹ jọ̀ọ́, ẹ jẹ́ kí n sọ fún yín,

      Ohun tí màá ṣe sí ọgbà àjàrà mi:

      Màá mú ọgbà tó yí i ká kúrò,

      Màá sì dáná sun ún.+

      Màá fọ́ ògiri olókùúta rẹ̀,

      Wọ́n sì máa tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀.

  • Jeremáyà 4:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Ẹ gbé àmì kan dúró* tó ń tọ́ka sí Síónì.

      Ẹ wá ibi ààbò, ẹ má sì dúró tẹtẹrẹ,”

      Nítorí mò ń mú àjálù bọ̀ láti àríwá,+ yóò sì jẹ́ ìparun tó bùáyà.

  • Ìsíkíẹ́lì 6:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ní gbogbo ibi tí ẹ̀ ń gbé, àwọn ìlú yóò di ahoro,+ wọ́n á wó àwọn ibi gíga, yóò sì di ahoro.+ Wọ́n á wó àwọn pẹpẹ yín, wọ́n á sì tú u ká, àwọn òrìṣà ẹ̀gbin yín máa pa run, wọ́n á wó àwọn ohun tí ẹ fi ń sun tùràrí, iṣẹ́ yín á sì pa rẹ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́