2 Àwọn Ọba 21:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Màá na okùn ìdíwọ̀n+ tí a lò fún Samáríà+ sórí Jerúsálẹ́mù àti irinṣẹ́ tí a fi ń mú nǹkan tẹ́jú* tí a lò fún ilé Áhábù,+ màá sì fọ Jerúsálẹ́mù mọ́ bí ẹni fọ abọ́ mọ́, màá nù ún, màá sì dojú rẹ̀ dé.+
13 Màá na okùn ìdíwọ̀n+ tí a lò fún Samáríà+ sórí Jerúsálẹ́mù àti irinṣẹ́ tí a fi ń mú nǹkan tẹ́jú* tí a lò fún ilé Áhábù,+ màá sì fọ Jerúsálẹ́mù mọ́ bí ẹni fọ abọ́ mọ́, màá nù ún, màá sì dojú rẹ̀ dé.+