-
Ìsíkíẹ́lì 7:12, 13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Àkókò á tó, ọjọ́ náà á dé. Kí ẹni tó ń ra nǹkan má ṣe yọ̀, kí ẹni tó sì ń ta nǹkan má ṣe ṣọ̀fọ̀, torí pé mo bínú sí gbogbo wọn.*+ 13 Tí ẹni tó ta nǹkan bá tiẹ̀ yè é, kò ní pa dà sí ìdí ohun tó tà, torí ìran náà kan gbogbo wọn. Kò sẹ́ni tó máa pa dà, kò sì sẹ́ni tó máa gba ara rẹ̀ là torí àṣìṣe òun fúnra rẹ̀.*
-