ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 6:29, 30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Ẹwìrì* wọn ti jóná.

      Òjé ló ń jáde látinú iná wọn.

      Ẹni tó ń yọ́ nǹkan mọ́ kàn ń ṣiṣẹ́ lásán ni,+

      Àwọn tí kò dára kò sì yọ́ kúrò.+

      30 Ó dájú pé fàdákà tí a kọ̀ ni àwọn èèyàn máa pè wọ́n,

      Nítorí Jèhófà ti kọ̀ wọ́n.”+

  • Jeremáyà 9:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Torí náà, ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí:

      “Màá yọ́ wọn mọ́, màá sì yẹ̀ wọ́n wò,+

      Àbí kí ni kí n tún ṣe sí ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi?

  • Málákì 3:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ó máa jókòó bí ẹni tó ń yọ́ fàdákà, tó sì ń fọ̀ ọ́ mọ́,+ ó sì máa fọ àwọn ọmọ Léfì mọ́; á sì yọ́ wọn mọ́* bíi wúrà àti fàdákà, ó sì dájú pé wọ́n á fi ọkàn òdodo mú ọrẹ wá fún Jèhófà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́