Sáàmù 20:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 A ó kígbe ayọ̀ nítorí àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ;+A ó gbé àwọn ọ̀págun wa sókè ní orúkọ Ọlọ́run wa.+ Kí Jèhófà dáhùn gbogbo ohun tí o béèrè. Sefanáyà 3:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Kígbe ayọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Síónì! Kígbe ìṣẹ́gun, ìwọ Ísírẹ́lì!+ Máa yọ̀, sì jẹ́ kí ayọ̀ kún inú ọkàn rẹ, ìwọ ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù!+ 15 Jèhófà ti mú àwọn ìdájọ́ kúrò lórí rẹ.+ Ó ti lé ọ̀tá rẹ dà nù.+ Ọba Ísírẹ́lì, Jèhófà, wà ní àárín rẹ.+ Ìwọ kò ní bẹ̀rù àjálù mọ́.+
5 A ó kígbe ayọ̀ nítorí àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ;+A ó gbé àwọn ọ̀págun wa sókè ní orúkọ Ọlọ́run wa.+ Kí Jèhófà dáhùn gbogbo ohun tí o béèrè.
14 Kígbe ayọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Síónì! Kígbe ìṣẹ́gun, ìwọ Ísírẹ́lì!+ Máa yọ̀, sì jẹ́ kí ayọ̀ kún inú ọkàn rẹ, ìwọ ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù!+ 15 Jèhófà ti mú àwọn ìdájọ́ kúrò lórí rẹ.+ Ó ti lé ọ̀tá rẹ dà nù.+ Ọba Ísírẹ́lì, Jèhófà, wà ní àárín rẹ.+ Ìwọ kò ní bẹ̀rù àjálù mọ́.+