Ẹ́kísódù 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nígbà yẹn, Mósè àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kọ orin yìí sí Jèhófà:+ “Jẹ́ kí n kọrin sí Jèhófà, torí ó ti di ẹni àgbéga.+ Ó taari ẹṣin àti ẹni tó gùn ún sínú òkun.+ 2 Sámúẹ́lì 22:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Dáfídì kọ ọ̀rọ̀ yìí lórin+ sí Jèhófà ní ọjọ́ tí Jèhófà gbà á lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀+ àti lọ́wọ́ Sọ́ọ̀lù.+ Àìsáyà 12:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ kọrin ìyìn sí* Jèhófà,+ torí ó ti ṣe àwọn ohun tó yani lẹ́nu.+ Ẹ jẹ́ kí gbogbo ayé mọ èyí.
15 Nígbà yẹn, Mósè àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kọ orin yìí sí Jèhófà:+ “Jẹ́ kí n kọrin sí Jèhófà, torí ó ti di ẹni àgbéga.+ Ó taari ẹṣin àti ẹni tó gùn ún sínú òkun.+
22 Dáfídì kọ ọ̀rọ̀ yìí lórin+ sí Jèhófà ní ọjọ́ tí Jèhófà gbà á lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀+ àti lọ́wọ́ Sọ́ọ̀lù.+