Sáàmù 48:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Gíga rẹ̀ rẹwà, ayọ̀ gbogbo ayé,+Òkè Síónì tó jìnnà réré ní àríwá,Ìlú Ọba Títóbi Lọ́lá.+ Sáàmù 48:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹ rìn yí ká Síónì; ẹ lọ káàkiri inú rẹ̀;Ẹ ka àwọn ilé gogoro rẹ̀.+