Sáàmù 78:34, 35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Àmọ́ tó bá ti bẹ̀rẹ̀ sí í pa wọ́n, wọ́n á wá a;+Wọ́n á pa dà, wọ́n á sì wá Ọlọ́run, 35 Wọ́n á rántí pé Ọlọ́run ni Àpáta wọn+Àti pé Ọlọ́run Ẹni Gíga Jù Lọ ni Olùdáǹdè* wọn.+ Hósíà 5:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Màá lọ, màá sì pa dà sí ipò mi títí wọ́n á fi gba ìyà ẹ̀bi wọn,Nígbà náà, wọ́n á wá ojú rere* mi.+ Nígbà tí wọ́n bá wà nínú ìdààmú, wọ́n á wá mi.”+
34 Àmọ́ tó bá ti bẹ̀rẹ̀ sí í pa wọ́n, wọ́n á wá a;+Wọ́n á pa dà, wọ́n á sì wá Ọlọ́run, 35 Wọ́n á rántí pé Ọlọ́run ni Àpáta wọn+Àti pé Ọlọ́run Ẹni Gíga Jù Lọ ni Olùdáǹdè* wọn.+
15 Màá lọ, màá sì pa dà sí ipò mi títí wọ́n á fi gba ìyà ẹ̀bi wọn,Nígbà náà, wọ́n á wá ojú rere* mi.+ Nígbà tí wọ́n bá wà nínú ìdààmú, wọ́n á wá mi.”+