Àìsáyà 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nígbà tí Jèhófà bá fọ ẹ̀gbin* àwọn ọmọbìnrin Síónì kúrò,+ tó sì fi ẹ̀mí ìdájọ́ àti ẹ̀mí tó ń jó* ṣan ìtàjẹ̀sílẹ̀ Jerúsálẹ́mù kúrò láàárín rẹ̀,+ Àìsáyà 48:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wò ó! Mo ti yọ́ ọ mọ́, àmọ́ kì í ṣe bíi ti fàdákà.+ Mo ti dán ọ wò* nínú iná ìléru ti ìyà, tí a fi ń yọ́ nǹkan.+
4 Nígbà tí Jèhófà bá fọ ẹ̀gbin* àwọn ọmọbìnrin Síónì kúrò,+ tó sì fi ẹ̀mí ìdájọ́ àti ẹ̀mí tó ń jó* ṣan ìtàjẹ̀sílẹ̀ Jerúsálẹ́mù kúrò láàárín rẹ̀,+
10 Wò ó! Mo ti yọ́ ọ mọ́, àmọ́ kì í ṣe bíi ti fàdákà.+ Mo ti dán ọ wò* nínú iná ìléru ti ìyà, tí a fi ń yọ́ nǹkan.+