-
Àìsáyà 7:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ìròyìn dé ilé Dáfídì pé: “Síríà ti lẹ̀dí àpò pọ̀ mọ́ Éfúrémù.”
Jìnnìjìnnì bá ọkàn Áhásì àti ti àwọn èèyàn rẹ̀, wọ́n ń gbọ̀n pẹ̀pẹ̀ bí àwọn igi inú igbó tí atẹ́gùn ń fẹ́ lù.
-