-
Jeremáyà 17:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí:
6 Yóò dà bí igi tó dá wà ní aṣálẹ̀.
Kò ní rí i nígbà tí ohun rere bá dé,
Ṣùgbọ́n àwọn ibi tó gbẹ nínú aginjù ni yóò máa gbé,
Ní ilẹ̀ iyọ̀ tí kò sí ẹnì kankan tó lè gbé ibẹ̀.
-