33 bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Wò ó! Màá fi òkúta+ ìkọ̀sẹ̀ kan àti àpáta agbéniṣubú lélẹ̀ ní Síónì, àmọ́ ẹni tó bá gbé ìgbàgbọ́ rẹ̀ lé e kò ní rí ìjákulẹ̀.”+
6 Torí Ìwé Mímọ́ sọ pé: “Wò ó! Màá fi òkúta àyànfẹ́ kan lélẹ̀ ní Síónì, òkúta ìpìlẹ̀ igun ilé tó ṣeyebíye, kò sì sí ẹni tó ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀ tí a máa já kulẹ̀.”*+