Àìsáyà 28:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Torí Jèhófà máa dìde bó ṣe ṣe ní Òkè Pérásímù;Ó máa gbéra sọ bó ṣe ṣe ní àfonífojì* tó wà nítòsí Gíbíónì,+Kó lè ṣe ìṣe rẹ̀, ìṣe rẹ̀ tó ṣàjèjì,Kó sì lè ṣe iṣẹ́ rẹ̀, iṣẹ́ rẹ̀ tó ṣàrà ọ̀tọ̀.+ Hábákúkù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Ẹ wo àwọn orílẹ̀-èdè kí ẹ sì kíyè sí i! Kí ẹnu yà yín bí ẹ ṣe ń wò wọ́n, kí ó sì jọ yín lójú;Torí ohun kan máa ṣẹlẹ̀ lásìkò yín,Tí ẹ ò ní gbà gbọ́ tí wọ́n bá tiẹ̀ sọ ọ́ fún yín.+
21 Torí Jèhófà máa dìde bó ṣe ṣe ní Òkè Pérásímù;Ó máa gbéra sọ bó ṣe ṣe ní àfonífojì* tó wà nítòsí Gíbíónì,+Kó lè ṣe ìṣe rẹ̀, ìṣe rẹ̀ tó ṣàjèjì,Kó sì lè ṣe iṣẹ́ rẹ̀, iṣẹ́ rẹ̀ tó ṣàrà ọ̀tọ̀.+
5 “Ẹ wo àwọn orílẹ̀-èdè kí ẹ sì kíyè sí i! Kí ẹnu yà yín bí ẹ ṣe ń wò wọ́n, kí ó sì jọ yín lójú;Torí ohun kan máa ṣẹlẹ̀ lásìkò yín,Tí ẹ ò ní gbà gbọ́ tí wọ́n bá tiẹ̀ sọ ọ́ fún yín.+