Àìsáyà 64:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ ní báyìí, Jèhófà, ìwọ ni Bàbá wa.+ Àwa ni amọ̀, ìwọ sì ni Ẹni tó mọ wá;*+Iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ni gbogbo wa.
8 Àmọ́ ní báyìí, Jèhófà, ìwọ ni Bàbá wa.+ Àwa ni amọ̀, ìwọ sì ni Ẹni tó mọ wá;*+Iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ni gbogbo wa.