ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nehemáyà 12:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Nígbà ayẹyẹ ṣíṣí ògiri Jerúsálẹ́mù, wọ́n wá àwọn ọmọ Léfì, wọ́n sì mú wọn wá sí Jerúsálẹ́mù láti gbogbo ibi tí wọ́n ń gbé kí wọ́n lè ṣe ayẹyẹ náà tayọ̀tayọ̀, pẹ̀lú orin ọpẹ́,+ pẹ̀lú síńbálì* àti àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù.

  • Àìsáyà 61:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Láti pèsè fún àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ torí Síónì,

      Láti fún wọn ní ìwérí dípò eérú,

      Òróró ayọ̀ dípò ọ̀fọ̀,

      Aṣọ ìyìn dípò ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn.

      A ó sì máa pè wọ́n ní igi ńlá òdodo,

      Tí Jèhófà gbìn, kó lè ṣe é lógo.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́