ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Hósíà 14:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Éfúrémù á sọ pé, ‘Kí ni mo tún fẹ́ wá lọ sọ́dọ̀ àwọn òrìṣà?’+

      Màá dáhùn, màá sì máa ṣọ́ ọ.+

      Màá dà bí igi júnípà tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀.

      Wàá sì máa rí èso lọ́dọ̀ mi.”

  • Sekaráyà 13:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé, “Ní ọjọ́ yẹn, èmi yóò pa orúkọ àwọn òrìṣà rẹ́ ní ilẹ̀ náà,+ wọn ò sì ní rántí wọn mọ́; èmi yóò sì mú àwọn wòlíì+ àti ẹ̀mí àìmọ́ kúrò ní ilẹ̀ náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́